| .......... |
.
|
AWON KOKO ORO FUN IPELE "GBIGBARADI"
.
|
nunlorla
Phil Bartle
nugormerderla Victor Tsikpe-Morttey
|
.
| Eyi
ti o se e se ki o lewu ju ninu imolara wa ninu ise wa na a ni ibinu ––
Bi a se le se amojuto re. Gege
bi aniyan, a ni awon imolara kan, ati pe ibinu je okan ninu won. O kuku dara bi eniyan
ba binu; ara pe a je eniyan eleran ara naa ni. Ko ye ki a ni idalebi okan tabi ki
oju ki o ti wa nigbati a ba ni imolara ibinu. Ibinu fun ra re je okan ninu ihuwasi
omo eniyan. A gbodo tewo gbaa nigba ti a ba n binu. |
. |
Sugbon
sa, ihuwasi wa nigba ti a ba n binu le ko ipa lori ise wa, boya a nse koriya fun
awon adugbo ni, a nse adari awon ti o fi ara won jin tabi a nse amojuto awon osise.
Nigba ti onibara kan, eni-ti-o-fi-ara-re-jin, osise tabi enikan ni adugbo ba se asise,
paapaa iru eyi ti o nipa lori afojusun wa, fun apaere, o see se ki a fe fi ibunu
han. Sugbon akokoyi gan an ni o ye ki a fi owo wo inu ki a si fi ara bale. |
.
| Nigba
ti a ba ri enikan ti o se asise ti o nipa lori abayori ti o wu wa, a nilo lati se
idamo pe bi a ti n rii n bi wa ninu ati pe ojuse wa ni lati se amojuto iru ibinu
bee. Ohun ti o dara ju ti a le se lesekese ni pe ki a jade lati rin kaakiri. Ti a
ko ba ni akoko ti o le to fun eyi, a gbodo jade lo si inu yara miran lai fi ibinu
wa han rara titi ti inu wa yio fi ro lasepe a je ki awon ti o mu inu bi wa ko firi
pe inu bi wa rara |
. |
Lehin
naa, nigba ti a ba ti fi ibinu wa si abe akoso, a wa le se amojuto ohun ti o mu ki
ibinu wa ki o ru soke. Ti o ba se pe okan ninu awon onibara wa ni ose asise tabi
eni-ti-o-fi-ara-re-jin, tabi osise, tabi enikan ni adugbo, a le se gegebi a ti se
apejuwe ninu awon koko oro, Asise.
Igbese yen yio mun-ina-doko nigba ti o ba je pe ibinu wa ti lo sile, ara wa ti bale,
a si ti wa ni alafia nigbati a gbee. |
.
| Awon
igba miran a ma n pe ni iwara pap ti iba ara eni gbe ni awujo, Lati inu oro ede Giriki
'anima' (aye, okan, ina, isipo pada ti a ko sese ronu si). Lati le ran lowo tabi
se koriya fun awujo ki o le fun rare te siwaju, ko o le wa laaye, ki o le dagba soke. |
. |
Awon
igba miran a ma n lo gege bi oro aropo fun sise koriya. Oro ti a pe ni iwara papa
(animation) tumo si pe ki a ran awujo kan lowo lati fi o fi owo-so-wo-po ki ori won
ki o si ya lati le se ohun ti o dara ti won fe se |
.
| Ogbon
ise fun Imunlokun Awujo tun mun iwara papa larin awujo te siwaju ni ipele kan si
nipa lilo awon ogbon ikoni lati tun fi kun ipa awujo, tabi awon elegbejegbe ti o
wa ni awujo, lati pinun, se eto, ati lati se amojuto nipa eto fun idagbasoke awujo
won. O ma n se idanileko fun awon eniyan ati awon olori ni awujo lori ati se eto
lati se ikawo idagbasoke awujo fun ra re. |
..... |
Beni
o tun ma a n ru awon osise ijoba, awon alakoso ni agbegbe, ati awon adari ni awujo
soke, ti o si n ko won lati yo owo kuro ninu ojuse bi i 'baba keresi' ti o n pese
ohun elo a mun-aye-derun. Won n ko lati fi ona han awon eniyan ni awujo bi a ti n
se idamo awon alumoni ti a ni ati lati gbe igbese lati pese ati lati se itoju awon
ohun elo a mun-aye-derun fun ibugbe awon aniyan. |
.
.
|
Aiko
ibi ara si nkan je okan ninu ohun marun gbogi okunfa
osi ati aile da ara eni mojuto.
|
.
| Ni
awon igba miran o ma ni se pule awon ero tabi igbekale ti o ni ewu. Sibe,
"Gbadura si Olorun, sugbon si tera mo oko titu de eti odo," ni owe awon ara Russia
kan ti
o n,
se afihan otito na a pe, bi o tile je pe owo Olorun ni a wa, sibe a ni ojuse lati
ran ara wa lowo. |
. |
Opolopo
ipa ise ni a da mo wa: lati yan, lati fi owo so owo po, lati se eto bi igbe aye gbadun
wa yio se dara sii; a ko gbodo lo ero wa nipa Olorun tabi Allah gege bii ohun ikewo
lati ma se ohun kankan. |
|
(
العربيّة: العربيّة,
বাংলা: উদাসীনতা,
Català: apatia,
Deutsch: Apathie,
Ελληνικά: απάθεια,
English: apathy,
Español: apatía,
Euskera: apatia,
Ewe: aiko ibi ara si nkan,
Filipino/Tagalog: pagsasawalang bahala,
Français: apathie,
Galego: apatía,
Italiano: apatia,
日本語: 無関心,
Kiswahili: usugu,
Malay: apati,
Português: apatia,
Română: apatie,
Somali: naceyb,
Tiên Việt: sự thờ ơ
)
|
.....
|
(
العربيّة: قدرة,
বাংলা : সক্ষমতাঃ,
Català: capacitat,
Deutsch: Macht, empowerment, die stärkung, leistungsfähigkeit,
Ελληνικά: δυνατότητες, ισχύς, δύναμη,
English: capacity, power, strength,
Español: capacidad, potenciación,
Euskera: gaitasuna,
Ewe: ipa,
Filipino/Tagalog: kakayahan, pagpapalakas,
Français: capacité, empowerment,
Galego: capacidade,
हिन्दी (Hindi): क्षमता,
Italiano: empowerment,
日本語: 容量, 強くする,
Kiswahili: uwezo,
Malay: kapasiti,
Português: capacidade, fortalecendo,
Română: capacitate,
Pyccкий: paзвития,
Somali: awooda,
Tiên Việt: năng lực, tăng cường
)
|
.
.
| Iyato
ti o wa laarin sise awari ipa eni ati mimu ipa eni dagba sii wa da lori ibi ti okun
fun idagbasoke ti wa. |
. |
Oro
ti a pe ni "mimu -ipa-eni dagba sii" tumo si pe awon ajo kan lati ode awujo naa tabi
agbari-jo-po kan ni yio se agbateru eto lati mu ki ipa awujo tabi agbari-jo-po bee
dagba si. |
.
| Ohun
ti o bi eleyi ni ero ti o da lorii "bi
a ti se eto ki awujo le dar sii." |
. |
Ni
idakeji, oro ti a pe ni "sise awari ipa eni" tumo si pe agbara fun idagba soke ninu
awujo bee wa ni inu awujo tabi agbari-jo-po bee. |
.
|
(
العربيّة العرب يّة: طو,
বাংলা : সক্ষমতা উন্নয়নঃ,
Deutsch: leistungsaufbau;
leistungsentwicklung,
Ελληνικά: ανάπτυξη δυνατοτήτων,
English: capacity development,
Español: desarrollo de la capacidad,
Euskera: gaitasunak garatzea,
Ewe: sise awari ipa eni,
Filipino/Tagalog: paglilinang ng kakayahan,
Français: renforcement des capacités, développement des capacités, bâtiment de capacité, développement de capacité, fortifier de la communauté,
Galego: desenvolvemento da capacidade,
हिन्दी (Hindi): षमता विकास, अधिकारिकरण,
Italiano: sviluppo della capacità,
日本語: 強くする, 容量の発展,
Kiswahili: kujengea uwezo,
Malay: pembangunan kapasiti,
Português: desenvolvimento de capacidade,
Română: dezvoltarea capacitatii,
Pyccкий: Рaзвития,
Somali: awoodsiinta,
Tiên Việt: Năng lực phát triển
)
|
.
| Akoko
ajoyo je akoko ti a nse akiyesi isele kan ti o mu ayipada ba aye enikan tabi ti ohun
kan. O je akoko fun aweje-wemu itagbangba. |
. |
Fun
oluse koriya, sise ajoyo pe a se aseyori lori ise ti a da owo le ni awujo je okan
ninu awon eroja pataki lati fun awujo lokun. Ni akoko yi ni a n se igboriyin ita
gbangba pe awon agbarijopo awon eniyan ni awujo lowo si idagbasoke nipa riran ara
eni lowo. |
.
| O
tun je akoko ti a ni ore ofe lati bere ni akotun; ani gbigbe dide eto sise koriya
leekan si. |
. |
Wo Sise
Koriya .
Wo Ajoyo.
|
|
(
العربيّة : الاحتفال,
বাংলা : উদ্যাপন,
Deutsch: feier,
Ελληνικά: Εορτασμός,
English: celebration,
Español: celebración,
Euskera: ospakizuna,
Ewe: ajoyo,
Filipino/Tagalog: pagdiriwang,
Français: célébration,
Galego: celebración,
日本語: お祝い,
Kiswahili: sherehe,
Malay: keraian,
Português: celebração,
Română: celebrare,
Pyccкий: Празднование,
Tiên Việt: sự khen ngợi
ردو: جشن
)
|
.
| Sise
iranlowo fun awon eniyan ti o se alaini tabi ti o nilo iranlowo je ohun ti o kari
aye, beeni a ri ipe fun sise eyi ninu iwe gbogbo esin ti o se pataki ni gbogbo agbaye.
Sugbon fifi fun ni je orisirisi. |
. |
Bi
ebun ti a fun enikan ba mun ki eniti a fi fun di
eni ti ko le da mu oju to ara re mo afi ki o gbara le o,
o ko se iranlowo lati fun iru eniyan bee ni okun, tabi ran an lowo lati di eni ti
o dagba to oju bo. |
.
| Bi
a ba fun alagbe kan ni owo ni jo popona, ohun ti a kan n se ni pe fun un ni idanileko
bi iru eni be yio se je alagbe sii. |
. |
Bi
a ba ro arojinle lori ise iranlowo ti a ba n se, ti o ba si ran iru eniti a n ran
lowo lati ni okun sii (wo itan Momodu ati okun ni ipele Awon
itan),
nigba naa iru ebun bee yio je eyi ti o wulo gidigidi. |
|
(
العربيّة:صدقة,
বাংলা : বদান্যতা,
Deutsch: Wohltätigkeit,
Ελληνικά: φιλανθρωπία,
English: charity,
Español: caridad,
Euskera: karitatea,
Ewe: aanu sise,
Filipino/Tagalog: kawang-gawa,
Français: charité,
Galego: caridade,
Italiano: carità,
日本語: 慈善,
Kiswahili: kujitolea,
Malay: amal,
Português: caridade,
Română: caritate,
Tiên Việt: lòng nhân từ
)
|
.
| Opolopo
ona ni a ti gba lo oro ti a pe ni "awujo". |
. |
Awon
oni imo ijinle nipa eda so pe itumo oro ti a pe ni awujo ni opolopo awon eniyan ninu
iru eda kookan,tabi oniruuru eda ti o yato, ti o wa laaye, ti o n fi aga gba ga,
ti o n fi owo so owo ki o le wa ni odindi ti o gbooro. |
.
| Lati
igba ti ti ero aye-lu-ja-ra [internet] ati imo nipa iba ara-eni-soro [information
technology], opolopo agbarijopo awon eniyan, ti won ni inu didun sii ni won n po
sii laisi gbedeke aala ti won si n ba ara won soro nipase ero naa. |
. |
Afojusun
wa ni inu awon ipele idani-leko lati ori ero aye lu jara yi, ni o da lori itumo awujo
si ohun ti a jin le pupo, awujo ti awon alaaye n gbe, eyi ti o ni gbedeke ibi ti
ile re fe de (a le fi kun eleyi nigba ti a ba n soro awon eniyan bii awon ti o n
da eran kiri), won wa ni ibasepo, fun apere, ni awujo ti ti o bere lati bii awon
aladugbo ni awon ilu nla, titi
o fi de awon abuleko ti o jinan rere. Wo Awon
olugbe ori ile. |
.
| Awujo
kii se akojopo awon eniyan olorijori lasan. O je ohun ti o ni emi ti o si ni ibasepo
pelu asa,
o je akojopo ibasepo larin awon eniyan, gbogbo ohun ti eniyan le ko ni eko. Ipa mefa
ti o pin si ni: imo ero, oro aje, agbara oselu, iba-ara-eni gbe po, awon ohun ti
a jo gbe ni aruge papo, igbagbo ati ero. Nipa eko kiko nikan ni a se le ni oye awon
nkan wonyi. |
. |
Gege
bii igi tabi ohun ti o ni iye ninu miran, bi awon eniyan ti se n da ara po mo awujo,
be naa ni awon kan n fii sile nipa iku tabi omo bibi, tabi fifi adugbo yen sile lo
si ibi miran. Sibe iru awujo bee ko ye wa ni aye ti o si ndagba sii. Ko si ni isokan
patapata ri, nitori pe o ni opolopo eya, ifagagbaga, idije, ati itaporogan ni arin
re. Ohun ti a n pe ni awujo po ju apao eyo kookan ninu awon ohun ti o wa ninu re.
Wo"Ki
ni a n pe ni awujo." |
.
|
(
العربيّة:مجتمع محلّي,
বাংলা : জনগোষ্ঠি,
Deutsch: gemeinde,
Ελληνικά: κοινότητα,
English: community,
Español: comunidad,
Euskera: komunitatea,
Ewe: awujo,
Filipino/Tagalog: komunidad,
Français: communauté,
Galego: comunidade,
Italiano: comunità,
日本語: 共同体,
Kiswahili: jamii,
Malay: komuniti,
Português: comunidade,
Pyccкий: Cooобщество,
Română: comunitate,
Somali: bulsho,
Tiên Việt: cộng đồng
)
|
.
|
AWON OHUN TI O DA LORI AWUJO: |
.
| Ki
is tabi agbarijopo to le da lori awujo, o gbodo je eyi ti gbongbo re wa ni iru awujo
bee,olugbe awujo bee ni ojuse be si ni awon ipinu ati eto nibe gbodo je eyi ti awon
ulogbe awujo bee fi enu ko si. |
. |
A
komle so pe ise kan tabi iranlowo lati ode iru awujo bee je eyi ti o da lori awujo
yen.Bee si ni, a ko le so pe tori a gba imoran lowo awon olori ni awujo kan ni o
le je ki iru ise beeje eyi ti o da lori awujo. |
.
| Iyato
nla ni o wa larin ise ti o da lori awujo ati eyi ti a kan se si iru awujo be. Ti
ile ise kn ba da ise kale ni awujo kan ( fun apere, ile iwosan, tabi iru eto miran),
o je eyi ti a kan da si awujo be ni. |
. |
Ti
yio ba je eyi ti o da lori wujo nitooto, akitiyan, kiko ile, ise, tabi apejopo, gbodo
je eyi ti a yan, mu, ti a si dari lati owo awon gbogbo gboo eniyan ni iru awujo bee(kii
kan se awon eka kan). Ohun ti o se pataki ni ki o je pe inu awujo bee ni a ti nse
gbogbo ipinu. |
.
|
(
العربيّة ائم على المجت مع المحلّي,
বাংলা : জনগোষ্ঠি ভিত্তিক,
Deutsch: gemeindenah,
Ελληνικά: βασισμένο στην κοινότητα,
English: community based,
Español: basado en la comunidad,
Euskera: komunitatean oinarritutako,
Ewe: awon ohun ti o da lori awujo,
Filipino/Tagalog: batay sa komunidad.
Français: fondé sur la communauté,
Galego: baseado na comunidade,
日本語: 共同体を基盤とする,
Italiano: community based,
Kiswahili: ilyo ya jamii,
Malay: berasaskan komuniti,
Português: baseado na comunidade,
Română: ancorata in comunitate,
Tiên Việt: nền
tảng, cơ sở của cộng đồng
)
|
|
APEJOPO TI O DA LORI AWUJO: |
.
| Apejopo
ti o da lori awujo (CBO) ni awon apejopo ti a da ti o si dagba larin awujo, ni ibi
ti awon eto ati igbese ti o siwaju ipinu sise ma tiowo awon olugbe inu awujo bee
wa agbajopo awon eniyan. |
. |
Ile
ise ti a da sile ti a si n se akoso ati awon ipinu re lati ode awujo le je eyi ti
o wa ni arin awujo sugbon ko da lori awujo. Wo adape oro ti pe ni, CBO. |
|
(
العربيّة: مؤسسة قائمة على المجتمع المحلّي,
বাংলা : জনগোষ্ঠি ভিত্তিক সংস্থা বা সংগঠন,
Deutsch: gemeindenahe organisation,
Ελληνικά: οργανισμός βασισμένος στην κοινότητα,
English: community based organization,
Español: organización basada en la comunidad,
Euskera: komunitatean oinarritutako elkartea,
Ewe: apejopo ti o da lori awujo,
Filipino/Tagalog: organisasyong batay sa komunidad (OBK),
Français: organisation a basé dans la communauté,
Galego: organización baseada na comunidade,
Italiano: organizzazione community based,
日本語: 共同体組織,
Kiswahili: miradi ya kijamii,
Malay: organisasi berasaskan komuniti,
Português: comunidade fundou organização,
Română: organizatie ancorata in comunitate,
Tiên Việt: cơ sở tổ chức của cộng đồng
)
|
|
ISODI TITUN TI O DA LORI AWUJO: |
.
| Ohun
ti Isodi titun, nihin, tumon si ni nipa ti ara (ni ti ibi), imolara tabi ni ti opolo
awon eniyan ti ara won ko da pe ni ona an tabi omiran. |
. |
Ni
ibi ti isodi titun yi ba ti da lori awujo, sise ipinu ati ojuse fun iranlowo awon
akanda eda ti o wa ni iru awujo bee yio wa lati inu awujo, kii se lati ode re. |
.
|
Wo
adape oro ti a pe ni, CBR.
|
|
(
العربيّة: إعادة التأهيل القائم على المجتمع المحلّي,
বাংলা : জনগোষ্ঠি ভিত্তিক পূনর্বাসন,
Deutsch: gemeindenahe Rehabilitation,
Ελληνικά: αποκατάσταση βασισμένη στην κοινότητα,
English: community based rehabilitation,
Español: rehabilitación basada en la comunidad,
Euskera: komunitatean oinarritutako erreabilitazioa,
Ewe: isodi titun ti o da lori awujo,
Filipino/Tagalog: rehabilitasyon batay sa komunidad,
Français: réadaptation a basé dans la communauté,
Galego: rehabilitación baseada na comunidade,
Italiano: riabilitazione community based,
日本語: 共同体を基盤とするリハビリテーション,
Kiswahili: Ukarabati wa kijamii,
Malay: pusat pemulihan berasaskan komuniti,
Português: reabilitação baseado na comunidade,
Română: rebilitarea ancorata in comunitate,
Tiên Việt: sự khôi phục lại cơ sở của cộng đồng
)
|
|
IGBON OWOSI LATI ODO AWON OLUGBE AWUJO: |
.
| Nigba
ti a ba n te enu mo pe igbon owo si kii si ohun kan naa pelu ilowosi (bi o tile je
wipe opo eniyan ni o ma n pee ni ohun kan naa), sibe a gbodo kiyesi pe mejeji ni
o s pataki. |
. |
Nigbati
ilowo si awon eniyan ni awujo ninu awon ipinu ti a n se ma n mu ki a so pe iru awon
akitiyan bee je eyi ti o da lori awujo, fifi ohun kan tabi omiran sile se pataki
lati ri pe awon olugbe adugbo bee ni imolara pe ajoni ni ohun ti a ba gbe se ni iru
awujo bee. Ki i se pe won ri gba lofe ni sugbon o na won ni ohun kan. |
.
| Imoran
ti agba ni pe, o kere tan, ida kan ninu ohun meji ti a nilo fun ise ni awujo ti a
n ran lowo ni o gbodo wa lati inu awujo bee fun ra re. Ni akoko, awon olugbe awujo
le ma wo iru eto yi pelu ibu- bojo. Sugbon alaye ti ao se ni pe o ye ki a se iwadi
iye ti ise afara-se awon eniyan ni awujo paapaa ku si. Iya lenu ni yio je nigba ti
won ba se awari pe ilowosi won je eyi ni o ni iye lori pupo. |
. |
A
o tun fi han won pe akoko ti awon eniyan n lo, paapaa julo, awon ti o wa ni awon
igbimo alase, ti won n se ipinnu tabi se eto lori awon ise sise, je akoko ti o ni
iye lori pupo. O ye ki a se idi-ye-le fun ise afara-se. Bee ni a o tun se alaye pe
opolopo igba ni o je pe a ma n din iye ti yan ati idoti ti awon eniyan ba fi sile
ku. o si ye ki a fun won ni ojulowo iye ti won ba je ni, gegebi ilowo si awon olugbe
awujo. |
|
(
العربيّة:مساهمة المجتمع المحلّي,
বাংলা : জনগোষ্ঠির অংশপ্রদান,
Deutsch: gemeindebeitrag,
Ελληνικά: κοινοτική συνεισφορά,
English: community contribution,
Español: contribución comunitaria,
Euskera: komunitatearen ekarpena,
Ewe: igbon owosi lati odo awon olugbe awujo,
Filipino/Tagalog: kontribusyon ng komunidad,
Français: contribution de la communauté,
Galego: contribución comunitaria,
Italiano: contributo della comunità,
日本語: 共同体の貢献,
Kiswahili: mchango wa jamii,
Malay: sumbangan komuniti,
Português: contribuição da comunidade,
Română: contributia comunitatii,
Tiên Việt: sự góp phần cho cộng đồng
)
|
.
| Nigba
ti awujo ba ndagba soke, o ma n po si. Wo oro ti a pe ni, Idagbasoke.
Ko se dandan ki o tumo si pe o n tobi sii tabi o n ni oro sii. Ohun ti o tumo si
ni pe o n dagba sii, o si n ni okun sii. |
. |
Niwon
igbati a ko ni so pe ododo ti a fatu ti ga si lehin ti a faa tu, bee na ni oluse
koriya nikan ko le mu ki awujo dagbasoke. Awoju fun ara re [gege bi ibugbe awon eniyan]
ni yio mun ara re dagbasokeOhun ti o le se ko ju ki o gba ni ni iyanju, se atilehin
fun ati se itona fun awon olugbe ni awujo . |
.
| Awon
eniyan kan ti ro pe ti a ba so wipe awujo ndagba soke sii, ohun ti o tumo si ni wipe
o ti n di oloro sii ––
anikun
lori iye owo ti olorijori nri. O seese ki o ri bee, sugbon, o ju bee lo. |
. |
Iyipada
ni, ni akoko ti awujo n te siwaju, ti awon ohun rere n po sii, ti agbara agba-ri-jo-po
n poo si, ti awon ayipada rere si n po si. |
.
|
Idagbasoke
tumo si didagba ni gbogbo origun mefa ti asa ni. O
yato si pe a n fun awujo ni okun sii. Bi o tile je pe alaye lori awon mejeji yato
si ara won, sugbon won ni ibasepo daada.
|
|
(
العربيّة:تطوير المجتمع المحلّي,
বাংলা : জনগোষ্ঠি উন্নয়ন,
Deutsch: gemeindeentwicklung,
English: community development,
Español: desarrollo comunitario,
Euskera: komunitatearen garapena,
Ewe: idagbasoke awujo,
Filipino/Tagalog: kalinagangg (kaunlaran) pangkomunidad,
Français: développement de la communauté,
Galego: desenvolvemento comunitario,
Italiano: sviluppo della comunità,
日本語: 共同体の発展,
Kiswahili: maendeleo ya jamii,
Malay: pembangunan komuniti,
Português: desenvolvimento da comunidade,
Română: dezvoltarea comunitatii,
Somali: horumarka bulshada,
Tiên Việt: sự phát triển của cộng đồng
)
|
.
|
Lati
kun awujo kan ni ipa lati dagba sii ninu ipa re lati ran ara re lowo.
|
.
|
O
ju pe a kan n se afikun awon ise tabi eto a mun aye derun bii ona, imototo, omi,
eto si iwe kika, ati itoju alaisan.
|
.
| O
tumo si okun sii ati agbara sii. O tumo si ogbon ise sii, ida ara eni loju sii, ati
imu-na-doko sii ninu eto sise. A ko le se ala-ba-pade-re nipa pe a n da awon ohun
elo jo lati odo awon alejo. O seese ki o di aseyoyi nipa awon ise sise ni awujo.
Sugbon aleyi yio seese nigba ti gbogb awon eniyan ni iru awujo bee ba lowo sii lati
ibere, lati se ipinnu lori ohun ti a o se, lati se awari awon alumoni ti o fi ara
sin ni iru awujo bee, ati
nipa riri awon ohun elo bii ohun ajo-ni lati ibere titi de opin. |
. |
Bi
o tile je pe ijoba le se iranwo lati mu ki eto iselu ki o gbooro sii, nipa sise awon
ofin ti yio fun awujo ni okun. Sugbon ipa lati se amulo awon ipinu to o da lori ofin
yio duro lorii ipa ise. ani agbara lati se ipinu nipa eto idagba-soke ara re, se
ipinu nipa ojo iwaju re. Agbara, okun, ipa, ipa ise,
ifun-ni-lokun. |
.
|
Idagbasoke
sii awujo tumo si ki awujo o ma a dagba sii ni gbogbo agbegbe mefa ti asa. O
yato si ifun awujo lokun ti o tumo si pe ki o ma ni okun sii. Bi o tile je pe iyato
wa larin itumo awon oro mejeji, sibe won ni afiwe ti o so won po.
|
|
(
العربيّة:تمكين المجتمع,
বাংলা : জনগোষ্ঠির ক্ষমতায়ন,
Deutsch: gemeindestärkung,
English: community empowerment,
Español: potenciación comunitaria,
Euskera: komunitatea sendotzea,
Ewe: ifun awujo lokun,
Filipino/Tagalog: pagsasakapangyarihan ng komunidad,
Français: fortifier de la communauté,
Galego: potenciación comunitaria,
Italiano: empowerment della comunità,
日本語: 共同体強化,
Malay: pemberdayaan komuniti,
Português: fortalecendo da comunidade,
Română: consolidarea coomunitatii,
Tiên Việt: sự uỷ quyền cộng đồng
)
|
|
IDANILEKO LORI SISE AKOSO AWUJO: |
.
| Awujo idanileko
lori sise akoso ni
a da oju re ko ona lati din ise ati osi ku, ona lati kun awon ti owo oya won ko po
ni awujo lowo nipa sise eto ati akoso awon ohun ini, awon ikole, ise sise ati eto
atunse. Iru idanileko yi kii kan se fun lati ko awon eniyan ni ogbon ise nikan tabi
lati se ito-ni-leti fun awon olorijori, sugbon fun ogbon amuse. |
. |
Idanileko,
gegebi ona lati fun awonawujo ti owo oya won kere ni okun sii, lati din ise ati osi
ku, lati se iwuri fun fun ilowo si awon eniyan, gege bi iran lowo fun eto iselu ti
o mu-na-doko, kuro ni ohun ti a le pe ni eto lati se ito-ni-leti ati lati se iranlowo
fun ogbon ise fun awon akeko. O tun ni ise
koriya ati ise
akoso. Eyi kii se idanileko ti o wopo. |
.
|
Lati
se agbekale iru idanileko yi ni ona ti o wopo ni lati je ki a ni ewu aile ko ni daradara,
lati se igbe-laru-ge fun ogbon ise dipo igbani ni iyanju, sise koriya ati eto ninu
eko kiko.
|
.
| idanileko
lori sise akoso ni
ona ti a n se yi ni a se eto re lati kun imu-na-doko awon alakoso ti o wa ni oke
patapata ati ni arin ni awon ile ise okoowo. |
. |
A
ti se atunse re nihin, a si ti se amunlo ogbo lati ko awon osise jo; ni pataki lati
se koriya fun ati lati fi okun si fun awon eniyan ni awujo ti owo oya won kere lati
wa papo, ki won se iranlowo fun ara won, pelu erongba lati yi awujo pada si rere. |
|
(
العربيّة:تدريب الإدارة المجتمعيّة,
বাংলা : জনগোষ্ঠি ব্যবস্থাপনা প্রশিক্ষণ
Deutsch: gemeinde-management-training,
English: community management training,
Español: adiestramiento para la gestión comunitaria,
Euskera: komunitate kudeaktearen trebakuntza,
Ewe: idanileko lori sise akoso awujo,
Filipino/Tagalog: pagsasanay as pamamahala ng komunidad,
Français: formation pour la gestion de la communauté,
Galego: formación para a xestión comunitaria,
Italiano: formazione in gestione di comunità,
Kiswahili: Mafunzo ya utawala wa jamii,
Malay: latihan pengurusan komuniti,
Português: formação para a gestão comunitária,
Română: instruirea comunitatii in management,
Tiên Việt: sự quản lý đào tạo cộng đồng
)
|
.
| Oro
ti a pe ni Ilowosi laarin awujo ju pe a kan da si ise sise, tabi a fi ohun kan sile: o ni se pule pe ki a da si ipinu sise, lati yan iru ise ti a o se ni arin awujo,
lati se eto fun, mu oju to sise re, se amojuto re, ati sise idari re. O yato si pe
a kan lowo si ati se ikojo ni arin awujo. |
. |
Sise
Iwuri fun Awon Eniyan ni Awujo. O
ma n se iwuri fun akitiyan awon eniyan ni awujo ti a fi oju sun, pelu erongba pe
ki awon eniyan o ko ipa ti o ni laari lori oro idagbasoke adugbo won. Eyi yio bere
nigba ti won ba ni owo ninu ipinu lati da owo le ise kan, tabi lati se koriya ti
yio mu ki awon eniyan o se ikojo alumoni ti won nilo ki won o si tun se eto bi awon
akitiyan won yio se lo. |
.
|
Ilowosi
ni awujo ma n se iwuri llati ri pe gbogbo eniyan (kii se die ninu won tabi awon ara
ita) ni o ni owo ninu ipinu sise ni awujo.
|
.
| Nipa
iru ogbon ise yi, a nse iwuri fun awon eniyan ni awujo, nitoripe ohun ti a ko ba
je iya fun kii le to ojo. Bee pelu, a tun maa n gba ijoba tabi awon oluranlowo lati
ode, ki won o ni apero pelu awon eniyan ni awujo nipa ohun ti won fe se; eyi ni a
n pe ni fifi ikun lu ikun pelu awon olugbe awujo. |
. |
Ilowosi
ni awujo ti a n se alaye re nihin kii se ohun kan naa pelu pe ki a se iko owojo tabi
tabi pe a kan se fifi ikun lu ikun pelu awon eniyan ( eyi ti o wopo larin opo awon
ile ise ti o n se iranlowo fun awon eniyan). Ilowo si nihin, tumo si ki a lowo si
ipinu sise, idari ati sise amojuto. |
|
(
العربيّة:مشاركة المجتم المحلّي,
বাংলা : জনগোষ্ঠির অংশগ্রহন,
Deutsch: gemeindepartizipation,
English: community participation,
Español: participación comunitaria,
Euskera: komunitatearen parte-hartzea,
Ewe: ilowosi awujo,
Filipino/Tagalog: Pakikilahok ng Komunidad,
Français: participation de la communauté,
Galego: participación comunitaria,
Italiano: partecipazione della comunità,
日本語: 共同体の参加,
Kiswahili: Ushiriki wa jamii,
Malay: penyertaaan komuniti,
Português: participação da comunidade,
Română: participarea comunitatii,
Somali: ka geyb galka bushada a,
Tiên Việt: sự tham gia của cộng đồng
)
|
.
| Nigba
ti ile ise kan ti o n se iranlowo fun awon eniyan ba lo lati se ifi ikun lu lu ikun
pelu awon olori ni awujo kan, opo igba ni won ma n beere boya iru awujo be n fe ki
a se agbakale ise kan fun won. Idan ti o si wopo ni "beeni" Iru
ile ise bee yio wa pada lo so fun awon alakoso ile ise won pe awon eniyan kopa ninu
ipinu sise. Eyi ko si ri be. |
. |
Ohun
ti won kan se ni lati se ifi ikun lu ikun, kii se pe awon eniyan ni awujo ni owo
si iru ipinu be, tabi ki won o yan lati se eto fun ise kan laarin awon ohun ti o
kan awujo yen gbon-gbon (yato si eyi ti o kan iru ile ise ti o fe se iranlowo fun
won). |
|
(
العربيّة:يستشير,
বাংলা : পরামর্শ গ্রহন,
Deutsch: beraten,
English: consult,
Español: consultar,
Euskera: aholkatu,
Ewe: ifi ikun lu ikun,
Filipino/Tagalog: konsulta,
Français: consulter,
Galego: consulta,
Italiano: consultazione,
Kiswahili: tatufa ushauri,
Malay: berunding,
Português: consulte,
Română: consultare,
Tiên Việt: tham khảo
)
|
.
| Awon
eniyan kan ko mo iyato ti o wa ni arin ilowosi ati ida owo si. Nigba ti opolopo eniyan
ba gbo ohun ti a pe ni ilowosi, se ni won ma n ro pe idawosi ni a n so. Ohun kan
ti won ma nro ni ise afi ara se ti awon eniyan yio se. |
. |
O
se eni ni anu pe opolopo igba ni o ma n je pe a o kan so awon eniya di eru ti a mu
ni agadi lati lati si ise tabi lati fi ohun kan tabi omiran sile( boya ile tabi ounje).
Atenumo iwe yi yato gede gede.Ilowosi nihin tumo si pe a kipa ninu ipinu sise , kii
se pe a kan da awon ohun elo jo. Wo idawo
si ni awujo. |
|
(
العربيّة:مساهمة,
বাংলা : সম্প্রদান,
Deutsch: beitrag,
English: contribution,
Español: contribución,
Euskera: ekarpena,
Ewe: ida owo si,
Filipino/Tagalog: kontribusyon,
Français: contribution,
Galego: contribución,
Italiano: contributo,
Kiswahili: mchango,
Malay: sumbangan,
Română: contributi,
Tiên Việt: sự đóng góp
)
|
|
IBANI WI NI ONA TI O LODI: |
.
| Okan
pataki ninu ohun amuns'ogbon ti o ye lati ko ni pe nigba ti a ba ri ohun kan ti o
lodi, ki a se ibaniwi ni ona ti o lodi ki i sabaa je eyi ti o to, tabi ona lati se
atunse ohun ti o lodi bee. Dipo bee, se ni o maa n mu ki nkan baje sii. |
. |
Ki
ni idi? Idi ni pe, nigba ti a ba n ba awon eniyan wi, se ni o maa n da bi eniti a
gbe ogun ti won, eru a si maa ba won. Iba-ni-wi ni ona ti o lodi maa n mun ki igboya
ninu ara eni ati iyi ara eni dinku. A
maa n gbe oju agan si eni ti o ba n ba ni wi ni ona ti o lodi, ati pe, dipo ki a
ko eko ki a si se atunse ti o ye, se ni a maa n wa idi fun ohun ti a se. |
.
| Ni
igba ti a ba n se koriya fun awon awujo, tabi a n se akoso awn ti o fi ara wo jin
lati se iranwo, tabi a n se akoso awon osise, a gbodo ko wo oye pe o seese ki won
o se asise, ki a si se imunrasile ona lati yanju gbogbo asise bee ti o le wa si aye,
ni ona to yio ran awon afojusun wa lowo. |
. |
Bi
a ba n fi ibinu wa han, ti a si n se ibaniwi eni ti o se asise ni ona ti o lodi,
seesi ki o kan je ona ti o rorun lati huwa ni akoko yi, sugbon iye ti a o san fun
iru ihawasi yi laipe yio po jojo. Lo wo awon koko oro: Awon
Asise, Ibinu,
ati Sandwich,
ati wiwa ona lati se atunse awon asise ti a se lai je pe a n ba ni wi ni ona ti o
lodi. |
.
|
(
العربيّة:نقد,
বাংলা : সমালোচনা,
Deutsch: kritik,
English: criticism,
Español: críticas,
Euskera: kritika,
Ewe: ibani wi ni ona ti o lodi,
Filipino/Tagalog: kritisismo o pamumuna,
Français: critique,
Galego: crítica,
Italiano: critica,
Kiswahili: pingamizi,
Malay: kritikan,
Português: crítica,
Română: critica,
Tiên Việt: phê bình
)
|
.
| Ju
oro orin ati ijo lasan, ohun ti a pe ni asa, ninu ti imo ijinle iba ara eni se, tumo
si gbogbo eto iba ara eni gbe po ni arin awujo, akojopo ohun gbogbo ti a ko nipa
ikohasi ati ihuwasi,ti o je akojopo asa iba ara eni gbe po ni awujo ti o ni eka mefa:
awon
ti o ni se pelu imo ero, awon
ti o ni se pelu eto oro aje, awon
ti o ni se pelu eto oselu, awon
ti o ni se pelu bi a se n ba ara eni gbe po, awon
ti o ni se pelu awon arojinle wa
ati awon
ti o ni se pelu iwoye wa nipa agbaye. |
. |
okan
pataki ninu eka asa ni "apere". Asa kii se ohun ti a bi mo eniyan; fifi awon apere
han ni o se alatagba re lati iran kan de omiran. Awon iigba miran, a maa n pe ni
"superorganic,"
nitoripe o n se akojopo awon ohun ti o ju oro ibi lo, tabi eniyan, ti o n se akojopo
ati agbateru asa. |
.
|
(
العربيّة:ثقافة,
বাংলা : ংস্কৃতি,
Deutsch: kultur,
English: culture,
Español: cultura,
Euskera: kultura,
Ewe: asa,
Filipino/Tagalog: kultura,
Français: culture,
Italiano: cultura,
Galego: cultura,
Kiswahili: tamaduni,
Malay: budaya,
Português: cultura,
Română: cultura,
Somali: dhaqanka,
Tiên Việt: văn hoá
)
|
|
IHUWASI DIDURO DE IRANLOWO SAA: |
.
| Ihuwasi
a n durode iranlowo saa ni ihuwasi ati igbagbo pe agbarijopo awon eniyan kan ko le
da yanju isoro ti won ni lai si pe won ri iranlowo gba lati ode. |
. |
Fifi-fun-ni
lasan a ma mun ki iru iwa yi tun buru sii. Wo: Ihuwasi
Diduro de Iranlowo Saa. |
|
(
العربيّة:متلازمة,
Bahasa Indonesia: dependensi,
বাংলা : পরনির্ভরতা (লক্ষণ),
Deutsch: Abhängigkeit (Syndrom),
Ελληνικά: Εξάρτησης,
English: dependency,
Español: (síndrome de) dependencia,
Euskera: mendekotasuna,
Ewe: ihuwasi diduro de iranlowo saa,
Filipino/Tagalog: pagtangkilik,
Français: syndrome de dépendance,
Italiano: dipendenza,
日本語: 依存,
Malay: ketergantungan,
Nederlands: afhankelijkheid,
Português: síndrome de dependência,
Română: dependenta,
Somali: ku tiirsanaanta,
Tiên Việt: phụ thuộc
ردو (Urdu): محتاجی کی لت,
)
|
.
| Opo
eniyan ni o ma n ro pe ohun ti idagbasoke tumo si ni pe ki ohun kan po si, sugbon
arin gbun-gbun re gan an ni iyipada ti o mu-na-d'oko. |
. |
Idagbasoke
tumo si lati dagba si, di-da-gba-si ju pe ki ohun kan o kan to sii lo; o tun tumo
si pe ki ohun kan o ni opolopo eka sii ki o si ni okun sii. |
.
| Nigba
ti aujo kan ba ndagba soke, a maa ni
okun
sii ati eka sii. |
. |
A
maa ni iyipada ninu eto iba ara eni gbe ni awujo. |
.
| Wo
"Asa."
Si oni imo ijinle lori eto oro aje, idagbasoke ko ju pe ki oro ilu tabi owo oya awon
eniyan ki o po sii (boya ti a ba woo ni ti gbogbo eniyan tabi ni ti olori-jori);
oni imo nipa ero le ri igbasoke bii ohun ti ko ju pe ki a ni akoso sii lori oro ohun
amu-se-agbara, tabi awon ohun elo ti o ja-fafa ti o si ni agbara sii. |
. |
Sugbon,
fun olusekoriya, eyo meji pere ni awon wonyi laarin awon ona mefa ti asa maa n gba
fi ara han ni
awujo
ti
o yi pada. Idagbasoke tumo si ayipada ti o maa n fi ara han ni awujo ni ona mefe
ti asa fi maa n fi ara han: imo ero, eto oro aje, eto ti oselu, biba ara eni se po,awon
ti o ni se pelu awon arojinle wa, awon ti o ni se pelu iwoye wa nipa agbaye. |
.
|
(
العربيّة:تطوير,
বাংলা : উন্নয়ন,
Deutsch: Entwicklung,
English: development,
Español: desarrollo,
Euskera: garapena,
Ewe: idagbasoke,
Filipino/Tagalog: kalinangan,
Français: développement,
Galego: desenvolvemento,
Italiano: sviluppo,
日本語: 発展,
Malay: pembangunan,
Português: desenvolvimento,
Română: dezvoltare,
Somali: horumarka,
Tiên Việt: sự phát triển
)
|
.
.
|
Ni
iwon bi a se le ri aworan awujo ninu asa won ati eto iba ara eni gbe po, awon eka
mefefa wonyi na nii se pelu awujo. Wo: Awon
Eka. |
|
(
العربيّة:أبعاد الثقاف ة,
বাংলা : সংস্কৃতির মাত্রা,
Deutsch: kulturdimensionen,
English: dimensions of culture,
Español: dimensiones de la cultura,
Euskera: kulturaren dimentsioak,
Ewe: awon eka asa,
Filipino/Tagalog: dimensyon ng kultura,
Français: dimensions de culture,
Galego: dimensións da cultura,
Italiano: dimensioni della cultura,
日本語: 文化の側面,
Malay: dimensi budaya,
Malay: dimensi budaya,
Română: dimensiunile culturii,
Somali: geybaha,
Tiên Việt: những yếu tố văn hoá
)
|
.
|
Arun
je okan ninu awon ona marun pataki fun ifi- ara-han
osi.
|
.
| Ina-wo
a din ku, yio si fi oju anu han, beeni yio si wulo sii fun awujo kan lati da owo
arun duro ju ati lati woo san lo. Ati lati da oju iwonba alumoni ti won ba ni ko
sise iwosan awon arun ti o wo po ti o n da oju ko opolopo awon eniyan ni ilu ju ki
a se inawo rira awon irin ise ati sise awari awon ogbon amu-se ti a fi le wo awon
oloro die (eyi ni idi ti ajo ti o n se agbateru fun eto iwosan ni gbogbo agbaye (WHO)
fi se atilehin fun agbekale eto iwoasan-alabode (PHC)). |
. |
Niwon
igba ti o ti mo eyi, iwo gege bi olusekoriya le pe awujo kan ni ija igbese won lati
koko lati ni ile-iwosan lia ronu jinle, ati lati le mun won se akiyesi iwa ologbon
ti o wa ninu ki won o koko yan lati ni eto fun omi ati imo-toto ki a le ba se idena
fun awon arun ti a le ko lati inu omi. |
|
(
العربيّة:مرض,
বাংলা : রোগ,
Deutsch: Krankheit,
English: disease,
Español: enfermedad,
Euskera: gaixotasuna,
Ewe: arun,
Filipino/Tagalog: sakit,
Français: maladie,
Galego: enfermidade,
Italiano: malattia,
日本語: 病気,
Malay: penyakit,
Português: doença,
Română: boala,
Somali: cudur,
Tiên Việt: dịch bệnh
)
|
.
| Aini
iwa omoluabi ati iwa iaje olooto. |
. |
Aije
olooto je okan ninu awon ona marun pataki fun ifi- ara-han
osi.
|
.
| Opolopo
akole ni o maa n ni, bii, iwa ibaje, iko-owo-na, ilo-ni-lowo-gba, ati ole. Eyi maa
n sele nigbati a ba da ori oro ti o ye ki a lo fun ilosiwaju ilu ko ibi miran fun
igbadun awon eniyan kereje kan ti won ti se lodi si igbekele ti awon eniyan ni ninu
won, ni ona aito ati ni koko. |
. |
Abayori
aini igbagbo ninu eni yi ni osi ati ki awon eniyan ma ni itara fun oro ilu. Idi
ni eyi ti iwo gege bi olusekoriya ati eniti o n se agbateru fun awon akojopo awon
eniyan, gbodo si igbelarege fu iwa ako-ya-wo, iwa omoluabi, ati jije olooto ni gbogbo
awon apejopo ti a ba n se amojuto won. |
|
(
العربيّة:فساد,
বাংলা : অসততা,
Deutsch: korruption, unehrlichkeit,
English: corruption, dishonesty,
Español: falta de honradez,
Euskera: zintzotasun eza,
Ewe: iwa aije olooto,
Filipino/Tagalog: di-matapat,
Français: malhonnêteté,
Galego: deshonestidade,
Italiano: disonestà,
日本語: 不正直,
Kiswahili: rushwa,
Malay: ketidakjujuran,
Português: desonestidade,
Română: necinste,
Somali: daacaddarro,
Tiên Việt: tính không thành thật,
)
|
|
SISE (kiko eko nipa sise): |
.
| Ninu
gbogbo awon ona ti a fi n ko eko (iwe kika, fifi eti sile gbo oro, wiwo (tabi sise
akiyesi)) eyi ti o mu-na-doko ju ni nipa "sise." Wo Awon
Ogbon ida-ni-leko. |
. |
Ara
awon ogbon ida-ni-leko nipa sise ni ki a kopa san an ninu sise ohun kan labe amojuto
enikan ti o n se ikoni, tabi ni ona miran nipa nini owo si tabi nipa kikopa ninu
ere sise. |
|
(
العربيّة:عمل (التعلّم عن طريق العمل),
বাংলা : কাজ করে শেখা,
Bahasa Indonesia: bekerja,
Deutsch: handeln,
Ελληνικά: Πράξη,
English: doing,
Español: practicar,
Euskera: egitea (eginez ikastea),
Ewe: sise,
Filipino/Tagalog: paggawa,
Français: faire,
Galego: facer,
हिन्दी (Hindi): लोकतन्त्र,
Italiano: learning by doing,
日本語: 実技,
Malay: membuat, melakukan,
Nederlands: doen,
Português: agir, faça, fazendo,
Română: a practica,
Tiên Việt: làm
اردو (Urdu): عمل,
)
|
.
| A
ma a n lo oro ti a pe ni iseda lati se iyato laarin aru eda ti aniyan je, boya 'ako'
tabi 'abo' |
. |
o
yato die si oro ti a pe ni "iru
eniyan"
wti amaa n lo lati se iyato laarin "okunrin" ati "obinrin." |
.
| Oro
ti pe iseda, ati awon adape ohun ti a pe ni ako ati abo yato gidigidi si ara won
laarinasa kan si omiran ati lati awujo kan si omiran. |
. |
Ohun
ti o kan wa ni ori oro iseda ni lati se ate-ju-mo bi iyato laarin won se le ni ipa
lori pipin agbara, iba-ara-eni-se- po ninu oro aje, ati iyato to o wa laarin awon
olori-io-ri awon eniyan ni ilu. |
.
| Awon
ohun wonyi je awon ohun ti o se pataki ti o maa n ko ipa lori awon awujo, a si maa
ni ipa lori iru ise ti olusekoriya kookan nse. |
. |
Gegebi
i amuye fun kiko eko nipa awujo kan, olusekoriya gbodo ni oye nipa awon ohun ti a
kara-ma-siki re, ihuwasi, ati awon ohun ti oye re ye awon olugbe awujo. |
.
|
Olusekiriya
tun gbodo sise lati ri pe a je ki awon iwa oselu ti ko to, ati iyato laarin bi oro
aje olorijori ti ri ki o din ku, gegebii ano pataki lati kan lati fun awujo ni agbara
sii.. Wo
iwe idanileko lori Iseda. Tun
wo: Ojo-ori,
Eya ati Okunrin oun obiririn.
|
|
(
العربيّة:جندر (تصنيف غير بيولوجي للجنس,
বাংলা : লিঙ্গ,
Deutsch: gender,
English: gender,
Español: género,
Euskera: generoa,
Ewe: iseda,
Filipino/Tagalog: pangkasarian o kasarian,
Français: genre,
Galego: xénero,
Italiano: genere,
日本語: ジェンダー,
Kiswahili: ujinsia,
Malay: gender,
Português: género,
Română: gen,
Somali: jandar,
Tiên Việt: giới tính
)
|
.
| Okan
ninu awon nkan marun ti o se gbogi ti o se okunfa osi
ni aimokan.
Opo eniyan ni a ma n ro oro ti a pe ni aimokan gege bii eebu. Ni pato, ohun ti a
n so ni pe awon eniyan kan ko ni imo lori awon ohun kan; ko si ohun itiju ninu iyen. |
. |
A
gbodo mo pelu, pe iwa aimokan ati iwa omugo kii se ohun kan naa, won yato gede gede
si ara won. Awon agbalagba le ko eko, sugbon a ko gbodo huwa si won bi a ti le se
si omode tabi ki a se won bi eni ti ko to awa. Bi a ba se bee a o se idiwo fun eko
kiko won. |
.
|
Aimokan
tumo si pe a ko mo ohun kan, iwa omugo tumo si pe a ko ni ogbon to lati mo ohun kan,
ati pe iwa ope tumo si sise tabi ai se ohun kan nigba ti a mon pe idakeji re ni o
to lati se. Iwa aimokan, iwa omugo ati iwa ope yato si ara won gede gede.
|
|
(
العربيّة: جهل,
বাংলা : অজ্ঞতা,
Deutsch: Unwissenheit,
English: ignorance,
Español: ignorancia,
Euskera: ezjakintasuna,
Ewe: aimokan,
Filipino/Tagalog: kamangmangan,
Français: ignorance,
Galego: ignorancia,
Italiano: ignoranza,
日本語: 無知識,
Malay: ketidaktahuan,
Português: ignorância,
Română: ignoranta,
Somali: jaahilnimo,
Tiên Việt: sự thiếu hiểu biết
)
|
.
.
| Riru-ni-soke.
Kii se ohun kan naa gan-gan pelu ki
a se eto ohun kan,
nitoripe ifi-si-ojuse gbodo koko sele (awon eniyan le rin bi o ti wu won) ki a to
le fun ni apejee sise koriya. |
. |
A
le ko sile bii "se koriya." Gege bii riruni
soke ki awujo le wa laaye,
ayafi pe riru-ni soke ki awujo le wa laaye yi tun ni ipa sise koriya ati sise akoso
ninu. Wo
"Fifi
ohun kan si ojuse." |
|
(
العربيّة:يعبيء,
বাংলা : সমবেতন,
Deutsch: mobilisieren,
English: mobilize,
Español: movilización,
Euskera: mobilizatu,
Ewe: se koriya,
Filipino/Tagalog: pagbibigay-buhay, pakilusin,
Français: mobilisez,
Galego: mobilizar,
Italiano: mobilitare,
Malay: memobilisasi,
Português: mobilizar,
Română: a mobiliza,
Somali: wacyigelinta,
Tiên Việt: vận động
)
|
.
| Oluse
koriya ni eni ti o n mun ki ori awon eniya ya lati gbe ohun kan se, lati je ki itesiwaju
ki o wa. Social animator. Akowe ti o n mojuto idagbasoke awujo tabi amu-gba-legbe
re. |
. |
Osise
fun eto awujo. Activist. Eniti o n se agbateru ilowosi awon eniyan ni awujo. Wo: Lati
Le Je Olusekoriya. |
|
(
العربيّة:شخص يقوم بالتعبئة,
বাংলা : সংগঠক,
Deutsch: mobilisieren, activist,
English: mobilizer, activist, animator,
Español: activista,
Euskera: mobilizatzailea,
Ewe: oluse koriya,
Filipino/Tagalog: pakilusin,
Français: mobilisateur,
Galego: activista,
Italiano: attivista,
日本語: 訓練士または助成人,
Kiswahili: ramsisha.
Malay: pemobilisasi,
Português: ativista,
Română: mobilizator,
Tiên Việt: người vận động
)
|
.
| Owo
ati oro ko tumo si ohun kan naa. Owo je apere asa ti gbogbo eniyan gbodo gbagbo ti
yio ba je ohun ti yio wulo. |
. |
Osee
se ki a loo gegebi odiwon fun oro, ona kan lati pin orotabi se pas-paro re, ati ona
lati se iko-pamo oro. (Wo "oro,"
ati Agbekale
fun Oro). |
.
|
(
لعربيّة:مال,
বাংলা : টাকা,
Deutsch: geld,
English: money,
Español: dinero,
Euskera: dirua,
Ewe: owo,
Filipino/Tagalog: pera,
Français: argent,
Galego: diñeiro,
日本語: 金銭,
Malay: wang,
Português: dinheiro,
Română: bani,
Somali: lacag,
Tiên Việt: tiền bạc
)
|
|
Bawo
ni a se n gbin olu? Se ni "a o kan fi won sinu okunkun, a o si maa fun won ni ajile
ti a fi igbe maalu se."
|
.
| Adape
oro ni eyi ti o tumo si odi-keji kiko
akoyawo. |
. |
Ni
opolopo igba ni o je pe adape oro ti o buru ti a pe ni igbe ako 'bovine' ni a maa
n lo dipo "igbe maalu". |
|
(
العربيّة:تعتيم,
বাংলা : মাশরুম পরিচর্যা,
Deutsch: pilzaufzucht,
English: mushroom treatment,
Español: setas, cultivo de setas,
Euskera: onddoaren tratamendua,
Ewe: hihu iwa bi olu,
Filipino/Tagalog: tratong kabuti,
Français: champignon, traitement de champignon,
Galego: o cultivo do champiñón,
Italiano: oscurità,
日本語: マッシュルーム扱い,
Malay: pengendalian cendawan,
Português: tratamento de cogumelo,
Română: "cultivarea" ciupercilor
)
|
.
| Osi
kii kan se ai ni owo lowo tabi aini owo oya, o ju ai ni ore ofe si awon ohun amu-aye-derun
bii omi, awon popo ona, eko, tabi ile iwosan. O je abayori “osi ti emi” ani ihuwasi
ai ni ireti, ai ni mo to lori awon ohun amu-soro ti o wa ni arowoto, gbigbe ara le
awon elomiran fun iranlowo, ai ni igboya ninu ara eni, idani-lagara, ai niawon ogbon
ise, ai ni igbagbo si ara eni ni awujo, ai see gbokanle, ati ai ni eto iko-ra-jo-papo
ni awujo; ni kukuru, ai ni eto akoso ti o mo-iyan-lori. Wo Awon
Okunfa Osi. |
. |
Osi,
gegebi i arun ti o n ti inu awujo la wa, pe fun awotan ti o ti inu awujo la wa; osi
kii kan se ai ni owo oya laarin awon oni-ori-je-ori awon eniyan. A le ka ese osi
ni ile nipa kiko awon eniyan jo ati nipa didari awon talaka si ona ati ran ara won
lowo, ati nipa nini okun sii (ifun-lokun)
nipa di da oju ko awon ipe-ni-ja ati sisegun won. Nitori naa, lati ka ese osi ni
ile, o pe fun mimu ki ise-akoso fi ese mu ile sii. |
|
(
العربيّة:فقر,
বাংলা : দরিদ্রতা,
Deutsch: Armut,
English: poverty,
Español: pobreza,
Euskera: txirotasuna,
Ewe: osi,
Filipino/Tagalog: Kahirapan,
Français: pauvreté,
Galego: pobreza,
Italiano: povertà,
日本語: 貧困,
Malay: kemiskinan,
Português: pobreza,
Română: saracie,
Somali: faqri,
Tiên Việt: sự nghèo đói
)
|
.
| Oro
ti a pe ni "dia owo owo duro" tumo si ki a mu irora kuro fun igba die. Ki
fun awon talaka ni owo ko da osi duro. |
. |
Gegebii
olusekoriya ti o fi ara re jin fun ati da oju ija ko orisun osi, dipo awon afihan
re, a gbodo yago fun yiyan ipa pe a kan n fun awon eniyan ni owo. |
|
(
لعربيّة:تسكين الفقر,
বাংলা : দারিদ্র উপশম,
Deutsch: Armutslinderung,
English: poverty alleviation,
Español: alivio de la pobreza,
Euskera: txirotasuna arintzea,
Ewe: dida owo osi duro,
Filipino/Tagalog: pagpapawi sa kahirapan,
Français: allégement de pauvreté,
Galego: alivio da pobreza,
Italiano: alleviare la povertà,
日本語: 貧困の軽減,
Malay: peringanan kemiskinan,
Português: alívio de pobreza,
Română: alinarea saraciei,
Somali: yareynta faqriga,
Tiên Việt: xoá đói giảm nghèo
)
|
.
| Gegebii
oluse koriya, lati gbe ogun ti iru arun ti o ti inu awujo la wa bii osi pe fun pe
ki a se agbe-ye-wo awon okunfa, ati gbigbe igbese lati lati mun awon okunfa yi kuro
Niwon bi osi se je arun ti o ti inu awujo la wa, ona
abayo re gbodo ti inu awujo la wa. |
. |
Awon
ona onibeji ti o fi ara pe ara won ti a le gba lati mun osi kuro (ti agbri-jo-po
gbogbo awujo, ati nipa ti ara eni) ni a o ri ninu awon ipele onibeji nihin: Gbogbo
Igbese Lati Se Koriya Fun Awujo,
ati Eto
Lati Pa Owo Wo'le. |
|
(
العربيّة:إستئصال الفقر,
বাংলা : দারিদ্র্য দূরিকরণ,
Deutsch: Armutsbeseitigung,
English: poverty eradication,
Español: erradicación de la pobreza,
Euskera: txirotasuna ezbatzea,
Ewe: sise imukuro osi,
Filipino/Tagalog: pagpuksa sa kahirapan,
Français: extirpation de pauvreté,
Galego: erradicación da pobreza,
Italiano: alleviare la povertà,
日本語: 貧困の撲滅,
Malay: penghapusan kemiskinan,
Português: erradicação de pobreza,
Română: eradicarea saraciei,
Somali: ciribtirka faqriga,
Tiên Việt: xoá triệt để cái nghèo
)
|
.
| Oro
ti a pe ni "adin-ku" tumon si lati mun ki ohun kan kere sii. Wo Agbekale
Fun Fifun Awujo Lokun. |
. |
Yato
fun ohun ti a pe ni "sise adin-ku" , ni eyi ti o n se am-ou-oto fun abayori
osi,
sise adin-ku ni a n wo gege bii ona ti o to lati se imukuro fun osi. |
|
(
العربيّة:تخفيض الفقر,
বাংলা : দারিদ্র বিমোচন,
Deutsch: Armutsreduzierung,
English: poverty reduction,
Español: reducción de la pobreza,
Euskera: txirotasuna murriztea,
Ewe: sise adin-ku fun osi,
Filipino/Tagalog: pagbabawas sa kahirapan,
Français: réduction de pauvreté,
Galego: redución da pobreza,
Italiano: riduzione della povertà,
日本語: 貧困の減少,
Malay: pengurangan kemiskinan,
Português: redução de pobreza,
Română: reducerea saracie,
Tiên Việt: giảm bớt nghèo đói
)
|
.
| Erongba
nipa eto iwosan alaboode, ti Ajo ti o n se eto ilera ni agbaye [WHO], se agbateru
re ti won si se atilehin fun, je okojopo awon ofin ati ona-ise ti awon talaka ati
awon eniyan ti o wa ni awon orile ede ti owo ti o n wole fun won kere ni inu didun
si. |
. |
Ninu
awon agbekale ti o wa ninu re ni sise atenumo lori owo nina fun eto ilera ti ko won
pupo fun awon aisan ti o wopo, awon ti o n se opolopo awon eniyan ni ilu, (dipo ki
a maa ko opolopo alumoni ti o won le ori eto iwosan fun awon olowo nikan. |
.
| Beeni
o tun se akiyesi pe ki a se amojuto ki arun ma wo ile din inawo ku ju sise iwosan
lo. a ni o maa n yori si mimun adinku ba iye awon eniyan ti o n ku, ati bi aisan
se n kolu awon eniyan, eyi ti o maa n munki o ni oro aje ni ara to o si tun ni aanu
omo eniyan ninu. |
. |
O
tun ni iwoye pe o seese lati se idanileko funawon eniyan lati ni imo die nipa eto
ilera ki won o si jade lo seaimojuto fun awon eniyan ni gbogbo awon ibi ti o wa ni
koro ni orile ede, ki won o si dari awon ti aisan won ta koko si awon ako-se-mo-se
eleto ilera ni awon ilu nla. |
.
| Iwoye
eto iwosan alabode (PHC) je eyi ti o se pataki fun awon oluse koriya ni awon orile
ede ti o je akuse, nitoripe gbogbo eniyan ni oye re gbodo ye, ati pe o je ona ti
o mu-na-doko lati se pipin awon alumoni kekere ti o wa. |
. |
Awon
agbekale ti eto iwosan alabode (PHC ) gbe ara le je awon eyi ti a le se amunlo re
fun agbekale awon ilepa miran ni awujo, bii awon ise awujo ti o wa fun itesiwaju
awon eniyan. Wo ohun ti a pe ni Eto
Iwosan Alaboode (PHC). |
|
(
العربيّة:رعاية صحّية أولي,
বাংলা : প্রাথমিক স্বাস্থ্য সেবা,
Deutsch: Primäre Gesundheitsversorgung,
English: primary health care,
Español: atención sanitaria primaria,
Euskera: lehen mailako osasun arreta,
Ewe: eto iwosan ala-boode,
Filipino/Tagalog: pangunahing kalingang pangkalusugan,
Français: santé primaire,
Galego: atención sanitaria primaria,
Italiano: assistenza sanitaria primaria,
日本語: プライマリー・ヘルス・ケア,
Malay: penjagaan kesihatan utama,
Português: cuidado médico primário,
Română: ingrijirea medicala primara,
Tiên Việt: chăm sóc sức khoẻ sơ cấp
)
|
|
RIRU-NI SOKE KI AWUJO LE WA LAAYE: |
.
| Riru-ni
soke Ki Awujo Le Wa Laaye tumo si pe ki a fi eemi iye sinu agbarijo waon ohun kan
bii awujo. |
. |
A
maa n pe ni "riru-ni soke fun iye" (sugbon ki a ma dapo pelu awon aworan cinima ti
o se ere omode "cartoons"). Wo Riru-ni
soke fun iye. |
|
(
العربيّة:تنشيط إجتماعي,
বাংলা : সামাজিক অনুপ্রেরণা,
Deutsch: Soziale Animation,
English: social animation,
Español: animación social,
Euskera: gizarte animazioa,
Ewe: riru-ni soke ki awujo le wa laaye,
Filipino/Tagalog: pagbibigay-buhay panlipunan,
Français: animation sociale,
Italiano: animazione,
日本語: 社会活発化, 強くする,
Malay: animasi sosial,
Português: animação social,
Română: animare sociala,
Tiên Việt: lòng nhiệt tình xã hội
)
|
|
(
العربيّة:تقوية,
বাংলা : শক্তিশালীকরন,
Deutsch: Empowerment, Macht, die stärkung, Stärken,
English: capacity development, empowerment, power, strengthening,
Español: capacidad, potenciación,
Euskera: indartzea,
Ewe: fifun ni lokun,
Filipino/Tagalog: pagpapalakas,
Français: capacité, empowerment,
हिन्दी (Hindi): षमता विकास अधिकारिकरण,
Italiano: empowerment,
日本語: 強くする,
Kiswahili: kujengea uwezo,
Malay: menguatkan,
Português: capacidade, desenvolvimento de capacidade, fortalecendo,
Română: dezvoltarea capacitatii, intarire,
Pyccкий: Рaзвития,
Somali: xoojinta,
Tiên Việt: tăng cường
)
|
––»«––
|